Ẹ́kísódù 25:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kí ẹ ṣe àgọ́ ìjọsìn àti gbogbo ohun tó máa wà níbẹ̀, kó rí bí ohun* tí màá fi hàn ọ́ gẹ́lẹ́.+ Ẹ́kísódù 25:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Rí i pé o ṣe wọ́n bí ohun* tí mo fi hàn ọ́ lórí òkè.+