-
1 Kíróníkà 21:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Àmọ́, Ọba Dáfídì sọ fún Ọ́nánì pé: “Rárá o, iye tó bá jẹ́ ni màá rà á, torí mi ò ní gba ohun tó jẹ́ tìrẹ kì n sì fún Jèhófà tàbí kí n fi rú àwọn ẹbọ sísun láìná nǹkan kan.”+
-