-
2 Kíróníkà 25:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) ni Amasááyà nígbà tó jọba, ọdún mọ́kàndínlọ́gbọ̀n (29) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jèhóádánì láti Jerúsálẹ́mù.+
-
-
2 Kíróníkà 25:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Nígbà tí ìjọba rẹ̀ ti fìdí múlẹ̀ dáadáa, ó pa àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tí wọ́n pa bàbá rẹ̀ ọba.+
-