-
2 Kíróníkà 30:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Lẹ́yìn náà, wọ́n pa ẹran ẹbọ Ìrékọjá ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kejì. Ìtìjú bá àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì, torí náà, wọ́n ya ara wọn sí mímọ́, wọ́n sì mú àwọn ẹbọ sísun wá sí ilé Jèhófà.
-