30Hẹsikáyà ránṣẹ́ sí gbogbo Ísírẹ́lì+ àti Júdà, ó tiẹ̀ tún kọ lẹ́tà sí Éfúrémù àti Mánásè,+ pé kí wọ́n wá sí ilé Jèhófà ní Jerúsálẹ́mù láti wá ṣe Ìrékọjá sí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+
10 Torí náà, àwọn asáréjíṣẹ́* lọ láti ìlú dé ìlú káàkiri ilẹ̀ Éfúrémù àti Mánásè,+ kódà wọ́n dé Sébúlúnì, àmọ́ àwọn èèyàn ń fi wọ́n rẹ́rìn-ín, wọ́n sì ń fi wọ́n ṣe yẹ̀yẹ́.+