34 Ìkùukùu* sì bẹ̀rẹ̀ sí í bo àgọ́ ìpàdé, ògo Jèhófà sì kún inú àgọ́ ìjọsìn náà.+35 Mósè ò lè wọnú àgọ́ ìpàdé torí pé ìkùukùu ò kúrò lórí àgọ́ náà, ògo Jèhófà sì kún inú àgọ́ ìjọsìn náà.+
10 Nígbà tí àwọn àlùfáà jáde láti ibi mímọ́, ìkùukùu+ kún ilé Jèhófà.+11 Àwọn àlùfáà kò lè dúró ṣe iṣẹ́ wọn nítorí ìkùukùu náà, torí pé ògo Jèhófà kún ilé Jèhófà.+