1 Kíróníkà 28:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nínú gbogbo àwọn ọmọ mi, torí àwọn ọmọ tí Jèhófà fún mi pọ̀,+ ó yan Sólómọ́nì+ ọmọ mi láti jókòó sórí ìtẹ́ ìjọba Jèhófà lórí Ísírẹ́lì.+ 1 Kíróníkà 29:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Sólómọ́nì jókòó sórí ìtẹ́ Jèhófà+ gẹ́gẹ́ bí ọba ní ipò Dáfídì bàbá rẹ̀, ó ṣàṣeyọrí, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ń ṣègbọràn sí i.
5 Nínú gbogbo àwọn ọmọ mi, torí àwọn ọmọ tí Jèhófà fún mi pọ̀,+ ó yan Sólómọ́nì+ ọmọ mi láti jókòó sórí ìtẹ́ ìjọba Jèhófà lórí Ísírẹ́lì.+
23 Sólómọ́nì jókòó sórí ìtẹ́ Jèhófà+ gẹ́gẹ́ bí ọba ní ipò Dáfídì bàbá rẹ̀, ó ṣàṣeyọrí, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ń ṣègbọràn sí i.