-
2 Kíróníkà 6:39Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
39 nígbà náà, láti ibi tí ò ń gbé ní ọ̀run, kí o gbọ́ àdúrà wọn àti ẹ̀bẹ̀ wọn pé kí o ṣojú rere sí àwọn,+ kí o sì ṣe ìdájọ́ nítorí wọn, kí o dárí ji àwọn èèyàn rẹ tó ṣẹ̀ ọ́.
-