-
2 Kíróníkà 8:12, 13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Lẹ́yìn náà, Sólómọ́nì rú àwọn ẹbọ sísun+ sí Jèhófà lórí pẹpẹ+ Jèhófà tí ó mọ síwájú ibi àbáwọlé.*+ 13 Ó ń ṣe ohun tí wọ́n máa ń ṣe lójoojúmọ́, ó sì ń mú ọrẹ wá gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Mósè pa ní ti àwọn Sábáàtì,+ àwọn òṣùpá tuntun+ àti àwọn àjọyọ̀ tó máa ń wáyé nígbà mẹ́ta lọ́dún,+ ìyẹn Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú,+ Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀+ àti Àjọyọ̀ Àtíbàbà.+
-