Òwe 16:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Tí inú Jèhófà bá dùn sí ọ̀nà èèyàn,Ó máa ń mú kí àwọn ọ̀tá rẹ̀ pàápàá wà ní àlàáfíà pẹ̀lú rẹ̀.+