Jeremáyà 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ègún ni fún ọkùnrin* tó gbẹ́kẹ̀ lé èèyàn lásánlàsàn,+Tó gbára lé agbára èèyàn,*+Tí ọkàn rẹ̀ sì pa dà lẹ́yìn Jèhófà.
5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ègún ni fún ọkùnrin* tó gbẹ́kẹ̀ lé èèyàn lásánlàsàn,+Tó gbára lé agbára èèyàn,*+Tí ọkàn rẹ̀ sì pa dà lẹ́yìn Jèhófà.