Àwọn Onídàájọ́ 11:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Mi ò ṣẹ̀ ọ́ rárá, ìwọ lo ṣe ohun tí kò dáa bí o ṣe wá gbógun jà mí. Kí Jèhófà Onídàájọ́+ ṣe ìdájọ́ lónìí láàárín àwọn èèyàn Ísírẹ́lì àti àwọn èèyàn Ámónì.’” 28 Àmọ́ ọba àwọn ọmọ Ámónì kò fetí sí ohun tí Jẹ́fútà ní kí wọ́n sọ fún un. Sáàmù 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Dìde nínú ìbínú rẹ, Jèhófà;Gbéra láti kojú àwọn ọ̀tá mi nínú ìbínú wọn;+Jí nítorí mi, kí o sì mú kí wọ́n ṣe ìdájọ́ òdodo.+
27 Mi ò ṣẹ̀ ọ́ rárá, ìwọ lo ṣe ohun tí kò dáa bí o ṣe wá gbógun jà mí. Kí Jèhófà Onídàájọ́+ ṣe ìdájọ́ lónìí láàárín àwọn èèyàn Ísírẹ́lì àti àwọn èèyàn Ámónì.’” 28 Àmọ́ ọba àwọn ọmọ Ámónì kò fetí sí ohun tí Jẹ́fútà ní kí wọ́n sọ fún un.
6 Dìde nínú ìbínú rẹ, Jèhófà;Gbéra láti kojú àwọn ọ̀tá mi nínú ìbínú wọn;+Jí nítorí mi, kí o sì mú kí wọ́n ṣe ìdájọ́ òdodo.+