-
2 Àwọn Ọba 7:15, 16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Wọ́n tẹ̀ lé wọn títí dé Jọ́dánì, àwọn ẹ̀wù àti àwọn nǹkan èlò tí àwọn ará Síríà jù dà nù bí wọ́n ṣe ń sá lọ kíjokíjo kún gbogbo ojú ọ̀nà. Àwọn òjíṣẹ́ náà pa dà, wọ́n sì ròyìn fún ọba.
16 Àwọn èèyàn náà bá jáde lọ, wọ́n sì kó àwọn nǹkan tó wà ní ibùdó àwọn ará Síríà, tó fi jẹ́ pé òṣùwọ̀n síà ìyẹ̀fun kíkúnná di ṣékélì kan, òṣùwọ̀n síà méjì ọkà bálì sì di ṣékélì kan, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Jèhófà.+
-