1 Àwọn Ọba 3:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọba lọ sí Gíbíónì láti rúbọ níbẹ̀, nítorí ibẹ̀ ni ibi gíga+ tí àwọn èèyàn mọ̀* jù lọ. Ẹgbẹ̀rún kan (1,000) ẹbọ sísun ni Sólómọ́nì rú lórí pẹpẹ náà.+
4 Ọba lọ sí Gíbíónì láti rúbọ níbẹ̀, nítorí ibẹ̀ ni ibi gíga+ tí àwọn èèyàn mọ̀* jù lọ. Ẹgbẹ̀rún kan (1,000) ẹbọ sísun ni Sólómọ́nì rú lórí pẹpẹ náà.+