1 Kíróníkà 24:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Bí a ṣe pín àtọmọdọ́mọ àwọn ọmọ Áárónì nìyí: Àwọn ọmọ Áárónì ni Nádábù, Ábíhù,+ Élíásárì àti Ítámárì.+ 1 Kíróníkà 26:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Bí wọ́n ṣe pín àwọn aṣọ́bodè+ nìyí: nínú àwọn ọmọ Kórà, Meṣelemáyà+ ọmọ Kórè látinú àwọn ọmọ Ásáfù.
24 Bí a ṣe pín àtọmọdọ́mọ àwọn ọmọ Áárónì nìyí: Àwọn ọmọ Áárónì ni Nádábù, Ábíhù,+ Élíásárì àti Ítámárì.+
26 Bí wọ́n ṣe pín àwọn aṣọ́bodè+ nìyí: nínú àwọn ọmọ Kórà, Meṣelemáyà+ ọmọ Kórè látinú àwọn ọmọ Ásáfù.