-
Jeremáyà 11:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Mo dà bí ọ̀dọ́ àgùntàn tí kò lágbaja tí wọ́n ń mú bọ̀ níbi tí wọ́n ti fẹ́ pa á.
Mi ò mọ̀ pé wọ́n ń gbèrò ohun búburú sí mi pé:+
“Ẹ jẹ́ ká pa igi náà àti èso rẹ̀ run,
Ká sì gé e kúrò ní ilẹ̀ alààyè,
Kí a má bàa rántí orúkọ rẹ̀ mọ́.”
-