11 Ààlà náà tún lọ dé gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Ẹ́kírónì+ lápá àríwá, wọ́n sì pààlà náà dé Ṣíkẹ́rónì, ó kọjá lọ sí Òkè Báálà, ó dé Jábínéélì, ààlà náà sì parí sí òkun.
12 Ààlà náà lápá ìwọ̀ oòrùn ni Òkun Ńlá+ àti èbúté rẹ̀. Èyí ni ààlà àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà ní ìdílé-ìdílé yí ká.