2 “Ẹ ka+ gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lọ́kọ̀ọ̀kan, ní ìdílé-ìdílé, agbo ilé bàbá wọn, kí ẹ fi orúkọ ka gbogbo ọkùnrin. 3 Kí ìwọ àti Áárónì fi orúkọ gbogbo àwọn tó lè dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì sílẹ̀, ní àwùjọ-àwùjọ, láti ẹni ogún (20) ọdún sókè.+