Ẹ́kísódù 30:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Bákan náà, tí Áárónì bá tan àwọn fìtílà náà ní ìrọ̀lẹ́,* kó sun tùràrí náà. Bí wọ́n á ṣe máa sun tùràrí ní gbogbo ìgbà níwájú Jèhófà jálẹ̀ àwọn ìran yín nìyẹn.
8 Bákan náà, tí Áárónì bá tan àwọn fìtílà náà ní ìrọ̀lẹ́,* kó sun tùràrí náà. Bí wọ́n á ṣe máa sun tùràrí ní gbogbo ìgbà níwájú Jèhófà jálẹ̀ àwọn ìran yín nìyẹn.