-
2 Kíróníkà 29:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Iye ẹran ẹbọ sísun tí ìjọ náà mú wá jẹ́ àádọ́rin (70) màlúù, ọgọ́rùn-ún (100) àgbò, igba (200) akọ ọ̀dọ́ àgùntàn, gbogbo èyí ni wọ́n fi rú ẹbọ sísun sí Jèhófà,+
-