2 Àwọn Ọba 20:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ní ti ìyókù ìtàn Hẹsikáyà àti gbogbo agbára rẹ̀ àti bí ó ṣe ṣe adágún odò+ àti ọ̀nà omi àti bí ó ṣe gbé omi wá sínú ìlú,+ ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Júdà?
20 Ní ti ìyókù ìtàn Hẹsikáyà àti gbogbo agbára rẹ̀ àti bí ó ṣe ṣe adágún odò+ àti ọ̀nà omi àti bí ó ṣe gbé omi wá sínú ìlú,+ ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Júdà?