Ẹ́sírà 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àmọ́, ojú Ọlọ́run ò kúrò lára* àwọn àgbààgbà Júù,+ wọn ò sì dá wọn dúró títí wọ́n fi kọ̀wé ránṣẹ́ sí Dáríúsì, tí òun náà sì fi ìwé àṣẹ ránṣẹ́ pa dà lórí ọ̀rọ̀ náà.
5 Àmọ́, ojú Ọlọ́run ò kúrò lára* àwọn àgbààgbà Júù,+ wọn ò sì dá wọn dúró títí wọ́n fi kọ̀wé ránṣẹ́ sí Dáríúsì, tí òun náà sì fi ìwé àṣẹ ránṣẹ́ pa dà lórí ọ̀rọ̀ náà.