73 Àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì, àwọn aṣọ́bodè, àwọn akọrin,+ àwọn kan lára àwọn èèyàn náà àti àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì pẹ̀lú gbogbo ọmọ Ísírẹ́lì yòókù bẹ̀rẹ̀ sí í gbé inú àwọn ìlú wọn.+ Nígbà tó fi máa di oṣù keje,+ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ti wà nínú àwọn ìlú wọn.+