Ẹ́sítà 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ní oṣù kìíní, ìyẹn oṣù Nísàn,* ọdún+ kejìlá Ọba Ahasuérúsì, wọ́n ṣẹ́ Púrì,+ (ìyẹn Kèké) níwájú Hámánì láti mọ ọjọ́ àti oṣù, ó sì bọ́ sí oṣù kejìlá, oṣù Ádárì.*+
7 Ní oṣù kìíní, ìyẹn oṣù Nísàn,* ọdún+ kejìlá Ọba Ahasuérúsì, wọ́n ṣẹ́ Púrì,+ (ìyẹn Kèké) níwájú Hámánì láti mọ ọjọ́ àti oṣù, ó sì bọ́ sí oṣù kejìlá, oṣù Ádárì.*+