Nehemáyà 13:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n ka ìwé Mósè sétí àwọn èèyàn,+ wọ́n sì rí i pé ó wà lákọsílẹ̀ pé àwọn ọmọ Ámónì àti àwọn ọmọ Móábù+ kò gbọ́dọ̀ wá sínú ìjọ Ọlọ́run tòótọ́ láé,+ Nehemáyà 13:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ inú Òfin náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í ya onírúurú àjèjì* tó wà láàárín Ísírẹ́lì sọ́tọ̀.+
13 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n ka ìwé Mósè sétí àwọn èèyàn,+ wọ́n sì rí i pé ó wà lákọsílẹ̀ pé àwọn ọmọ Ámónì àti àwọn ọmọ Móábù+ kò gbọ́dọ̀ wá sínú ìjọ Ọlọ́run tòótọ́ láé,+
3 Nígbà tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ inú Òfin náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í ya onírúurú àjèjì* tó wà láàárín Ísírẹ́lì sọ́tọ̀.+