-
1 Kíróníkà 24:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Dáfídì àti Sádókù+ látinú àwọn ọmọ Élíásárì àti Áhímélékì látinú àwọn ọmọ Ítámárì pín wọn sí àwùjọ-àwùjọ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ìsìn wọn.
-
-
1 Kíróníkà 24:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 ìkẹta fún Hárímù, ìkẹrin fún Séórímù,
-
-
Ẹ́sírà 2:39Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
39 àwọn ọmọ Hárímù+ jẹ́ ẹgbẹ̀rún kan ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017).
-