-
1 Kíróníkà 24:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Dáfídì àti Sádókù+ látinú àwọn ọmọ Élíásárì àti Áhímélékì látinú àwọn ọmọ Ítámárì pín wọn sí àwùjọ-àwùjọ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ìsìn wọn.
-
-
1 Kíróníkà 24:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 ìkẹẹ̀ẹ́dógún fún Bílígà, ìkẹrìndínlógún fún Ímérì,
-
-
Ẹ́sírà 10:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Látinú àwọn ọmọ Ímérì,+ Hánáánì àti Sebadáyà;
-