25 Matanáyà,+ Bakibúkáyà, Ọbadáyà, Méṣúlámù, Tálímónì àti Ákúbù+ jẹ́ aṣọ́bodè+ tó ń ṣọ́ àwọn yàrá tí wọ́n ń kó nǹkan pa mọ́ sí lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹnubodè. 26 Àwọn yìí ṣiṣẹ́ nígbà ayé Jóyákímù ọmọ Jéṣúà + ọmọ Jósádákì àti nígbà ayé Nehemáyà gómìnà àti Ẹ́sírà+ tó jẹ́ àlùfáà àti adàwékọ.