-
2 Àwọn Ọba 17:33, 34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Nípa bẹ́ẹ̀, wọ́n ń bẹ̀rù Jèhófà, àmọ́ àwọn ọlọ́run wọn ni wọ́n ń sìn bí wọ́n ti ń ṣe nínú ẹ̀sìn* àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti kó wọn wá.+
34 Títí di òní yìí, ẹ̀sìn* wọn àtẹ̀yìnwá ni wọ́n ń ṣe. Kò sí ìkankan lára wọn tó sin* Jèhófà, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ìkankan lára wọn tó tẹ̀ lé ìlànà rẹ̀ àti ìdájọ́ rẹ̀, wọn ò sì pa Òfin àti àṣẹ tí Jèhófà fún àwọn ọmọ Jékọ́bù mọ́, ẹni tí Ó yí orúkọ rẹ̀ pa dà sí Ísírẹ́lì.+
-