Nehemáyà 7:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Mo wá ní kí Hánáánì+ arákùnrin mi máa bójú tó Jerúsálẹ́mù pẹ̀lú Hananáyà olórí Ibi Ààbò,+ torí òun ló ṣe é fọkàn tán jù lọ, ó sì bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́+ ju ọ̀pọ̀ àwọn míì lọ.
2 Mo wá ní kí Hánáánì+ arákùnrin mi máa bójú tó Jerúsálẹ́mù pẹ̀lú Hananáyà olórí Ibi Ààbò,+ torí òun ló ṣe é fọkàn tán jù lọ, ó sì bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́+ ju ọ̀pọ̀ àwọn míì lọ.