-
Ẹ́kísódù 40:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Torí ìkùukùu Jèhófà máa ń wà lórí àgọ́ ìjọsìn náà ní ọ̀sán, iná sì máa ń wà lórí rẹ̀ ní òru, gbogbo ilé Ísírẹ́lì sì máa ń rí i, bí wọ́n ṣe ń lọ láti ibì kan sí ibòmíì lẹ́nu gbogbo ìrìn àjò wọn.+
-