Nehemáyà 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn yìí ni àwọn èèyàn ìpínlẹ̀* tí wọ́n pa dà lára àwọn tó wà nígbèkùn, àwọn tí Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì kó lọ sí ìgbèkùn,+ àmọ́ tí wọ́n pa dà sí Jerúsálẹ́mù àti Júdà nígbà tó yá, kálukú pa dà sí ìlú rẹ̀,+ Nehemáyà 7:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 àwọn ọmọ Pahati-móábù,+ látinú àwọn ọmọ Jéṣúà àti Jóábù+ jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjì ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́jọ àti méjìdínlógún (2,818);
6 Àwọn yìí ni àwọn èèyàn ìpínlẹ̀* tí wọ́n pa dà lára àwọn tó wà nígbèkùn, àwọn tí Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì kó lọ sí ìgbèkùn,+ àmọ́ tí wọ́n pa dà sí Jerúsálẹ́mù àti Júdà nígbà tó yá, kálukú pa dà sí ìlú rẹ̀,+
11 àwọn ọmọ Pahati-móábù,+ látinú àwọn ọmọ Jéṣúà àti Jóábù+ jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjì ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́jọ àti méjìdínlógún (2,818);