Nehemáyà 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n sọ pé: “Àwọn tó ṣẹ́ kù sí ìpínlẹ̀* Júdà, tí wọ́n yè bọ́ lóko ẹrú wà nínú ìṣòro ńlá, ìtìjú sì bá wọn.+ Àwọn ògiri Jerúsálẹ́mù ti wó lulẹ̀,+ wọ́n sì ti dáná sun àwọn ẹnubodè rẹ̀.”+ Ìdárò 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn ọ̀nà tó lọ sí Síónì ń ṣọ̀fọ̀, nítorí kò sí ẹni tó ń bọ̀ wá sí àjọyọ̀.+ Gbogbo ẹnubodè rẹ̀ di ahoro;+ àwọn àlùfáà rẹ̀ ń kẹ́dùn. Ẹ̀dùn ọkàn ti bá àwọn wúńdíá* rẹ̀, ó sì wà nínú ìbànújẹ́ ńlá. Ìdárò 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àwọn ẹnubodè rẹ̀ ti rì wọlẹ̀.+ Ọlọ́run ti ba ọ̀pá ìdábùú rẹ̀ jẹ́, ó sì ti ṣẹ́ ẹ. Ọba rẹ̀ àti àwọn ìjòyè rẹ̀ wà láàárín àwọn orílẹ̀-èdè.+ Kò sí òfin;* kódà àwọn wòlíì rẹ̀ kò rí ìran láti ọ̀dọ̀ Jèhófà.+
3 Wọ́n sọ pé: “Àwọn tó ṣẹ́ kù sí ìpínlẹ̀* Júdà, tí wọ́n yè bọ́ lóko ẹrú wà nínú ìṣòro ńlá, ìtìjú sì bá wọn.+ Àwọn ògiri Jerúsálẹ́mù ti wó lulẹ̀,+ wọ́n sì ti dáná sun àwọn ẹnubodè rẹ̀.”+
4 Àwọn ọ̀nà tó lọ sí Síónì ń ṣọ̀fọ̀, nítorí kò sí ẹni tó ń bọ̀ wá sí àjọyọ̀.+ Gbogbo ẹnubodè rẹ̀ di ahoro;+ àwọn àlùfáà rẹ̀ ń kẹ́dùn. Ẹ̀dùn ọkàn ti bá àwọn wúńdíá* rẹ̀, ó sì wà nínú ìbànújẹ́ ńlá.
9 Àwọn ẹnubodè rẹ̀ ti rì wọlẹ̀.+ Ọlọ́run ti ba ọ̀pá ìdábùú rẹ̀ jẹ́, ó sì ti ṣẹ́ ẹ. Ọba rẹ̀ àti àwọn ìjòyè rẹ̀ wà láàárín àwọn orílẹ̀-èdè.+ Kò sí òfin;* kódà àwọn wòlíì rẹ̀ kò rí ìran láti ọ̀dọ̀ Jèhófà.+