-
Ẹ́sírà 3:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Torí náà, Jéṣúà àti àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ pẹ̀lú Kádímíélì àti àwọn ọmọ rẹ̀, ìyẹn àwọn ọmọ Júdà, dara pọ̀ láti máa bójú tó àwọn tó ń ṣiṣẹ́ ní ilé Ọlọ́run tòótọ́, bákan náà, àwọn ọmọ Hénádádì+ àti àwọn ọmọ wọn pẹ̀lú àwọn arákùnrin wọn, tí àwọn náà jẹ́ ọmọ Léfì dara pọ̀ mọ́ wọn.
-