15 Ṣálúnì ọmọ Kólíhósè, olórí ní agbègbè Mísípà+ tún Ẹnubodè Ojúsun + ṣe; ó kọ́ ọ, ó ṣe òrùlé rẹ̀, ó sì gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ sí i àti àwọn ìkọ́ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọ̀pá ìdábùú rẹ̀, ó tún ṣàtúnṣe ògiri Adágún+ Ṣélà tó lọ sí Ọgbà Ọba+ títí dé Àtẹ̀gùn+ tó sọ̀ kalẹ̀ látinú Ìlú Dáfídì.+