2 Jéṣúà+ ọmọ Jèhósádákì pẹ̀lú àwọn tí wọ́n jọ jẹ́ àlùfáà àti Serubábélì+ ọmọ Ṣéálítíẹ́lì+ pẹ̀lú àwọn arákùnrin rẹ̀ dìde, wọ́n sì mọ pẹpẹ Ọlọ́run Ísírẹ́lì, kí wọ́n lè máa rú àwọn ẹbọ sísun lórí rẹ̀, gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ nínú Òfin Mósè,+ èèyàn Ọlọ́run tòótọ́.