1 Kíróníkà 23:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Lẹ́yìn náà, Dáfídì ṣètò* wọn sí àwùjọ-àwùjọ+ gẹ́gẹ́ bí àwọn ọmọ Léfì ṣe wà: Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+ 1 Kíróníkà 25:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Síwájú sí i, Dáfídì àti àwọn olórí àwùjọ àwọn tó ń ṣiṣẹ́ ìsìn ya àwọn kan lára àwọn ọmọ Ásáfù, Hémánì àti Jédútúnì+ sọ́tọ̀ láti máa fi háàpù, àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín+ àti síńbálì*+ sọ tẹ́lẹ̀. Orúkọ àwọn tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn yìí ni,
6 Lẹ́yìn náà, Dáfídì ṣètò* wọn sí àwùjọ-àwùjọ+ gẹ́gẹ́ bí àwọn ọmọ Léfì ṣe wà: Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+
25 Síwájú sí i, Dáfídì àti àwọn olórí àwùjọ àwọn tó ń ṣiṣẹ́ ìsìn ya àwọn kan lára àwọn ọmọ Ásáfù, Hémánì àti Jédútúnì+ sọ́tọ̀ láti máa fi háàpù, àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín+ àti síńbálì*+ sọ tẹ́lẹ̀. Orúkọ àwọn tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn yìí ni,