Jeremáyà 31:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Gbogbo àfonífojì* àwọn òkú àti ti eérú* pẹ̀lú gbogbo ilẹ̀ onípele títí dé Àfonífojì Kídírónì,+ títí lọ dé igun Ẹnubodè Ẹṣin,+ lápá ìlà oòrùn, yóò jẹ́ ohun mímọ́ fún Jèhófà.+ A kò ní fà á tu láé, bẹ́ẹ̀ ni a kò ní ya á lulẹ̀.”
40 Gbogbo àfonífojì* àwọn òkú àti ti eérú* pẹ̀lú gbogbo ilẹ̀ onípele títí dé Àfonífojì Kídírónì,+ títí lọ dé igun Ẹnubodè Ẹṣin,+ lápá ìlà oòrùn, yóò jẹ́ ohun mímọ́ fún Jèhófà.+ A kò ní fà á tu láé, bẹ́ẹ̀ ni a kò ní ya á lulẹ̀.”