-
Ẹ́sítà 4:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 “Gbogbo àwọn ìránṣẹ́ ọba àti àwọn èèyàn tó wà ní àwọn ìpínlẹ̀ abẹ́ àṣẹ ọba ló mọ̀ pé, tí ọkùnrin tàbí obìnrin èyíkéyìí bá wọlé lọ bá ọba ní àgbàlá inú+ láìjẹ́ pé ọba pè é, òfin kan ṣoṣo tí wọ́n máa tẹ̀ lé ni pé: Kí wọ́n pa onítọ̀hún; àyàfi tí ọba bá na ọ̀pá àṣẹ wúrà+ sí i ni kò ní kú. Ó sì ti tó ọgbọ̀n (30) ọjọ́ báyìí tí wọn ò tíì pè mí sọ́dọ̀ ọba.”
-
-
Ẹ́sítà 8:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ọba na ọ̀pá àṣẹ wúrà sí Ẹ́sítà,+ ni Ẹ́sítà bá dìde, ó sì dúró níwájú ọba.
-