-
Àìsáyà 38:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Mo fira mi lọ́kàn balẹ̀ títí di àárọ̀.
Ó ń fọ́ gbogbo egungun mi bíi kìnnìún;
Ò ń mú mi wá sí òpin+ láti ojúmọmọ títí di òru.
-