Diutarónómì 28:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Wàá máa táràrà kiri ní ọ̀sán gangan, bí afọ́jú ṣe máa ń táràrà torí ó wà lókùnkùn,+ o ò sì ní ṣàṣeyọrí nínú gbogbo ohun tí o bá ń ṣe; wọ́n á máa lù ọ́ ní jìbìtì, wọ́n á sì máa jà ọ́ lólè léraléra, kò ní sẹ́ni tó máa gbà ọ́ sílẹ̀.+
29 Wàá máa táràrà kiri ní ọ̀sán gangan, bí afọ́jú ṣe máa ń táràrà torí ó wà lókùnkùn,+ o ò sì ní ṣàṣeyọrí nínú gbogbo ohun tí o bá ń ṣe; wọ́n á máa lù ọ́ ní jìbìtì, wọ́n á sì máa jà ọ́ lólè léraléra, kò ní sẹ́ni tó máa gbà ọ́ sílẹ̀.+