-
Jóòbù 36:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Àwọn tí kò mọ Ọlọ́run* nínú ọkàn wọn máa ń di ìbínú sínú.
Wọn kì í kígbe fún ìrànlọ́wọ́ kódà nígbà tó bá dè wọ́n.
-
-
Àìsáyà 33:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
‘Èwo nínú wa ló lè gbé níbi tí iná tó ń jẹni run wà?+
Èwo nínú wa ló lè bá ọwọ́ iná tí kò ṣeé pa gbé?’
-