1 Kíróníkà 29:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nítorí àjèjì àti àlejò ni a jẹ́ níwájú rẹ, bí gbogbo àwọn baba ńlá wa ti jẹ́.+ Nítorí àwọn ọjọ́ wa lórí ilẹ̀ ayé da bí òjìji,+ kò sí ìrètí kankan. Sáàmù 102:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn ọjọ́ mi dà bí òjìji tó ń pa rẹ́ lọ,*+Mo sì ń rọ bíi koríko.+ Sáàmù 144:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Èèyàn dà bí èémí lásán;+Àwọn ọjọ́ rẹ̀ dà bí òjìji tó ń kọjá lọ.+
15 Nítorí àjèjì àti àlejò ni a jẹ́ níwájú rẹ, bí gbogbo àwọn baba ńlá wa ti jẹ́.+ Nítorí àwọn ọjọ́ wa lórí ilẹ̀ ayé da bí òjìji,+ kò sí ìrètí kankan.