-
Jóòbù 18:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Àní, a máa pa iná ẹni burúkú,
Ọwọ́ iná rẹ̀ kò sì ní tàn.+
-
-
Jóòbù 18:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Pańpẹ́ máa mú un ní gìgísẹ̀;
Ìdẹkùn á sì mú un.+
-