Diutarónómì 32:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+ Sáàmù 11:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí olódodo ni Jèhófà;+ ó nífẹ̀ẹ́ àwọn iṣẹ́ òdodo.+ Àwọn adúróṣinṣin yóò rí ojú* rẹ̀.+ Sáàmù 139:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mo yìn ọ́ nítorí pé lọ́nà tó ń bani lẹ́rù ni o ṣẹ̀dá mi tìyanutìyanu.+ Àgbàyanu ni àwọn iṣẹ́ rẹ,+Mo* mọ èyí dáadáa. Dáníẹ́lì 9:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Torí náà, Jèhófà wà lójúfò, ó sì mú àjálù bá wa, torí Jèhófà Ọlọ́run wa jẹ́ olódodo nínú gbogbo iṣẹ́ tó ti ṣe; síbẹ̀, a ò ṣègbọràn sí ohùn rẹ̀.+ Ìfihàn 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n ń kọ orin Mósè+ ẹrú Ọlọ́run àti orin Ọ̀dọ́ Àgùntàn+ náà, pé: “Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè,+ àwọn iṣẹ́ rẹ tóbi, ó sì kàmàmà.+ Òdodo àti òótọ́ ni àwọn ọ̀nà rẹ,+ Ọba ayérayé.+
4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+
14 Mo yìn ọ́ nítorí pé lọ́nà tó ń bani lẹ́rù ni o ṣẹ̀dá mi tìyanutìyanu.+ Àgbàyanu ni àwọn iṣẹ́ rẹ,+Mo* mọ èyí dáadáa.
14 “Torí náà, Jèhófà wà lójúfò, ó sì mú àjálù bá wa, torí Jèhófà Ọlọ́run wa jẹ́ olódodo nínú gbogbo iṣẹ́ tó ti ṣe; síbẹ̀, a ò ṣègbọràn sí ohùn rẹ̀.+
3 Wọ́n ń kọ orin Mósè+ ẹrú Ọlọ́run àti orin Ọ̀dọ́ Àgùntàn+ náà, pé: “Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè,+ àwọn iṣẹ́ rẹ tóbi, ó sì kàmàmà.+ Òdodo àti òótọ́ ni àwọn ọ̀nà rẹ,+ Ọba ayérayé.+