Òwe 2:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ní ti àwọn ẹni burúkú, a ó pa wọ́n run kúrò ní ayé,+Ní ti àwọn oníbékebèke, a ó fà wọ́n tu kúrò nínú rẹ̀.+ Jeremáyà 25:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 ‘Ariwo kan á dún títí dé ìkángun ayé,Nítorí Jèhófà ní ẹjọ́ kan pẹ̀lú àwọn orílẹ̀-èdè. Òun fúnra rẹ̀ á ṣe ìdájọ́ gbogbo àwọn èèyàn.*+ Á sì fi idà pa àwọn ẹni burúkú,’ ni Jèhófà wí.
22 Ní ti àwọn ẹni burúkú, a ó pa wọ́n run kúrò ní ayé,+Ní ti àwọn oníbékebèke, a ó fà wọ́n tu kúrò nínú rẹ̀.+
31 ‘Ariwo kan á dún títí dé ìkángun ayé,Nítorí Jèhófà ní ẹjọ́ kan pẹ̀lú àwọn orílẹ̀-èdè. Òun fúnra rẹ̀ á ṣe ìdájọ́ gbogbo àwọn èèyàn.*+ Á sì fi idà pa àwọn ẹni burúkú,’ ni Jèhófà wí.