Jóòbù 38:29, 30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Látinú ilé ọlẹ̀ ta ni yìnyín ti jáde,Ta ló sì bí yìnyín wínníwínní ojú ọ̀run,+30 Nígbà tó dà bíi pé òkúta ló bo omi,Tí ojú ibú omi sì dì gbagidi?+
29 Látinú ilé ọlẹ̀ ta ni yìnyín ti jáde,Ta ló sì bí yìnyín wínníwínní ojú ọ̀run,+30 Nígbà tó dà bíi pé òkúta ló bo omi,Tí ojú ibú omi sì dì gbagidi?+