-
Jeremáyà 46:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ẹ gòkè lọ, ẹ̀yin ẹṣin!
Ẹ sá eré àsápajúdé, ẹ̀yin kẹ̀kẹ́ ẹṣin!
Kí àwọn jagunjagun jáde lọ,
Kúṣì àti Pútì, tí wọ́n mọ apata lò,+
Pẹ̀lú àwọn Lúdímù,+ tí wọ́n mọ ọrun tẹ̀,* tí wọ́n sì mọ̀ ọ́n lò,+
-
Jeremáyà 47:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Nígbà tí pátákò àwọn akọ ẹṣin rẹ̀ bá ń kilẹ̀,
Tí kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ ń dún
Tí àgbá kẹ̀kẹ́ rẹ̀ ń rọ́ gìrìgìrì,
Àwọn bàbá kò tiẹ̀ ní bojú wẹ̀yìn wo àwọn ọmọ wọn,
Nítorí ọwọ́ wọn ti rọ,
-
Hábákúkù 1:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Àwọn ẹṣin ogun wọn ń bẹ́ gìjàgìjà;
Ọ̀nà jíjìn làwọn ẹṣin wọn ti wá.
Wọ́n já ṣòòrò wálẹ̀ bí ẹyẹ idì tó fẹ́ yára gbé oúnjẹ.+
-
-
-
-
-