-
Jeremáyà 46:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ẹ fi ìjánu sí ẹṣin, kí ẹ sì gùn ún, ẹ̀yin agẹṣin.
Ẹ lọ dúró sí àyè yín, kí ẹ sì dé akoto.*
Ẹ dán aṣóró, kí ẹ sì wọ ẹ̀wù irin.
-