2 Kíróníkà 32:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Ẹ jẹ́ onígboyà àti alágbára. Ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì jáyà nítorí ọba Ásíríà+ àti gbogbo ọ̀pọ̀ èèyàn tó wà pẹ̀lú rẹ̀, torí àwọn tó wà pẹ̀lú wa pọ̀ ju àwọn tó wà pẹ̀lú rẹ̀.+ Sáàmù 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mi ò bẹ̀rù ẹgbẹẹgbẹ̀rún èèyànTí wọ́n yí mi ká láti gbógun tì mí.+
7 “Ẹ jẹ́ onígboyà àti alágbára. Ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì jáyà nítorí ọba Ásíríà+ àti gbogbo ọ̀pọ̀ èèyàn tó wà pẹ̀lú rẹ̀, torí àwọn tó wà pẹ̀lú wa pọ̀ ju àwọn tó wà pẹ̀lú rẹ̀.+